Home / Àṣà Oòduà / Arákùnrin kan ni ó na ìyàwó rè, tí ó sì ba àwò ara ré je.

Arákùnrin kan ni ó na ìyàwó rè, tí ó sì ba àwò ara ré je.

Arákùnrin kan ni a gbó wípé ó na ìyàwó rè tí ó sì dá àpá si lára, ládúrú bí won ti se n kó wa ní èkó lórí bí a se le gbé lókoláya tó.

Bí ó tilè jé wípé aláse ni oko lórí aya rè ,ìyan kò so wípé kí ó so ìyàwó rè di bàrà kí ó so ó di bènbé ìlú, bí oko se láse lórí aya ni ìyàwó náà láse lórí oko.
Èyin okùnrin wa e jòwó e jé kí a máa fi ìfé bá àwon aya wa gbé, nítorí àwon ni alásirí wa, ìròrùn igi náà ni ìròrùn eye, èyí túmò sí wípé ìròrùn aya ní ìròrùn oko rè.
E jé kí á dékun ìjà láàrin lókoláya( say no domestic violence).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.