Home / Àṣà Oòduà / Arákùnrin Oyinbo yí ló fé ìyàwó rè tí ó jé omo Edo, tí won sì se ìgbéyàwó ìbílè Alárédè.

Arákùnrin Oyinbo yí ló fé ìyàwó rè tí ó jé omo Edo, tí won sì se ìgbéyàwó ìbílè Alárédè.

Òyìnbó kò mà le mú ojú kúrò lórò lára àwon omoge orílè èdè Nìjíríà rárá, nítorí won mò wípé arewà ni won, won sì mo ìké oko se, bí kò bá jé béè ogún-l’ógbòn àwon òyìnbó ni ó ti fé omo orílè èdè Nìjíríà yí.
E wo arákùnrin yí níbi ayeye ìgbéyàwó ti ìbílè ti òun àti olorì rè, tí a kò bá rí kò omobìnrin náà rewà ó pò jú, e wo bí ó se dàbí eni wípé won bí Òyìnbó náà mó aso ìbílè náà ni.
Èyí wú ni lórí púpò.

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.