Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.

   Isé rí èro ayélujára n se kojá òye èdá…

Àwon oko pèlú Aya àfésónà yí ti setán láti di tokotayà ní òsè péréte si léyìn tí won làdé lórí èro ayélujára (Facebook). Gégé bí Ijeoma Nwosu se so, ó ní òun pàdé olólùfé òun Chukwuma Inya-Agha ní odún méta séyìn léyìn ìgbà tí ó ka èróngbà àwon èèyàn lórí oun tí ó pín ní orí (Facebook).
Báyìí won ti se tán àti féra ní ojó kesàn-án osù kejìlá (9/12/2017).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo