Home / Àṣà Oòduà / Àwon òdó se ayeye ojó ìbí fún Ààre télè, Goodluck Ebele Jonathan ní ìgbà tí ó pé omo ogóta odún (60th).

Àwon òdó se ayeye ojó ìbí fún Ààre télè, Goodluck Ebele Jonathan ní ìgbà tí ó pé omo ogóta odún (60th).

Ogúnl’ógbòn àwon òdó ni won péjú níbi ayeye ojó ìbí Ààre orílè èdè Nàíjíríà télè, Goodluck Ebele Jonathan láti ba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo ogota odún.
E wo àwòrán n’ísàlè .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo