Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán Yvonne Nelson àti Jamie Roberts, bàbá omo rè níbi tí won tí n fi ìfé hàn sí ara won.

Àwòrán Yvonne Nelson àti Jamie Roberts, bàbá omo rè níbi tí won tí n fi ìfé hàn sí ara won.

   E wo àwòrán èyí tí ó fi ìfé hàn láàrin olólùfé méjì, ògbóntàrigì òsèré orílè èdè Ghana Yvonne Nelson pèlú bàbá omo rè tí ó jé ayà àwòrán láti orílé èdè Britain.

Jamie Robert wo okò òfuruufú láti lo bá olólùfé rè ní Ghana.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.