Home / Aarin Buzi / Awon wo ni Kunle Afolayan sepe fun?

Awon wo ni Kunle Afolayan sepe fun?

Ogbontarigi onise tiata, Kunle Afolayan ti fepe ranse fun awon ti kii ra ojulowo fiimu ti won se sita, to je wi pe ayederu ti awon onisedudu n se ni won ra. “To o ba ra ayederu sinima mi tabi to kopi re si ori flash, adura re ko ni gba. Nitori ayederu n pa ise wa lara” – Kunle Afolayan
Kunle Afolayan ti n ya fiimu re tuntun lowo, “The CEO” la gbo wi pe aimoye owo ni awon banki ko sile fun un lati ri fiimu naa se lojulowo yato si gbarogudu to kungboro

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*