Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán Oritsefemi àti Nabila Fash léyìn tí won se ìgbéyàwó ìbílè ní òwúrò tán kí ó tó di wípé won se ti alárédè.

Àwòrán Oritsefemi àti Nabila Fash léyìn tí won se ìgbéyàwó ìbílè ní òwúrò tán kí ó tó di wípé won se ti alárédè.

Àwòrán Oritsefemi àti Nabila Fash léyìn tí won se ìgbéyàwó ìbílè ní òwúrò tán kí ó tó di wípé won se ti alárédè. Oritsefemi àti ìyàwó rè tí tè síwájú fún ìgbéyàwó alárédè .
E wo Nabila Fash bí ó se dàbí egbin, nse ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó eléyìí tí gbogbo won kàn n se ìyàwó yí.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo