Home / Àṣà Oòduà / Covid-19- kó̩ ló pa Babatunde Oke

Covid-19- kó̩ ló pa Babatunde Oke

Covid-19 ko lo pa Babatunde Oke
Owuro oni ni won kede iku Alaga ijoba ibile Onigbongbo, Ogbeni Babatunde Oke.


Gbogbo iroyin to gbee ni ajakale arun coronavirus lo paa. Won ni baba naa se aisan ranpe ni nnkan bii ose meta seyin sugbon ti ara ti ya.
Won ni alaga yii se odun ileya pelu awon ololufe ati ore pelu ojulumo ni asiko odun naa.

Asiko yii gan-an ni awon olutele oloogbe naa ni ategun tun raaye wo ara re. Won ni bi aisan naa se wo baba naa mole niyen. Eyi mu ki won sare gbee lo si ile iwosan aladaani Kan.


Ile-iwosan naa ni alaga naa ti gbemi mi ti o si je Olorun nipe.
Awon olutele Alaga naa ni won ba IROYIN OWURO soro, won ni covid-19 ko lo pa baba naa. Won ni awon si wa nibi igbokusi ni Yaba lati se oku naa lojo fun igba die.


Awon alaba-sise oloogbe naa ni ti o ba je covid-19 lo pa baba naa, ile-iwosan ko ni fi oku naa sile bee ni won ko si nii gba ki awon toju iru oku naa.

About ayangalu

x

Check Also

À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí

À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí Fẹ́mi Akínṣọlá Àtubọ̀tán ayé ń kànkùn gbọ̀ngbọ̀n.Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n ní bí a bá ń rin ìrìnàjò, kí á wo ẹni tí à ń bá lọ, nítorí àti ilé àti òde ni apani wà. Ìròyìn àgbọ́ Tomi lójú pòròpòrò nípa Monsuru Tajudeen ẹni ọgbọ̀n ọdún kan tí ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọṣun lórí ẹ̀sùn pé ó ń pa ènìyàn tí ó sì ń ta ẹ̀yà ara wọn fáwọn tó ń ...