Home / Àṣà Oòduà / E wa wo ohun ti omo Naijiria kan an se lori afara

E wa wo ohun ti omo Naijiria kan an se lori afara

Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi lori, mo si sun moo lati foro wa lenu wo. ori re ko daru, eniyan tori re pe ni. Laipe, n maa salaye ohun ti mo mubo. Sugbon ohun kan lo damiloju, iye awon eniyan ti won ba Naijiria je le po, sugbon awon olododo eniyan kan si wa ti won tun un se pelu inu kan.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.