Home / Àṣà Oòduà / Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun

Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun

Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won fe lo gege bi igbakeji re. Sugbon titi di akoko yii, a ko le ti so boya Faleke faramo aba lati di igbakeji okunrin naa.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.