Home / Àṣà Oòduà / Flavour àti àwon omo rè obìnrin méjì, Sophia àti Gabrielle Okoli ti ya àwòrán tí ó ya ni lénu .

Flavour àti àwon omo rè obìnrin méjì, Sophia àti Gabrielle Okoli ti ya àwòrán tí ó ya ni lénu .

Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé èyí tí a mò sí Flavour ti gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán àwon omo rè tí ó pè ní olorì, nígbà tí ó se ayeye ojó ìbí rè pèlu Sophia àti Gabrielle.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.