Home / Àṣà Oòduà / “Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee

“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee

Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni  maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe,  Dokita Akintunde ti wa ninu wahala nla bayii.

Onibara Yem-Kem to n gbe loke okun yii tun so wi pe, owo ti dokita isegun ibile naa ni ati awon alagbara to feyinti lo je ki won ri ina iroyin wahala to ko si naa pamole patapata ti ko fi lu seti awon omo araye.

 
 E je ka tesiwaju lati ka alaye arabirin naa bo se ko lede geesi:

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo