Home / Àṣà Oòduà / Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.

Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.

    Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A gbàdúrà kí elédùà mú won lára dá.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.