Home / Àṣà Oòduà / Ile itura alaja metalelogota (63) n jona bayii niluu Dubai

Ile itura alaja metalelogota (63) n jona bayii niluu Dubai

Bi a se n mura lati wo inu odun tuntun lo, ni aisun odun taa wayii, ile itura alaja metalelogota (63) kan an jona lo lowolowo bayii ni ilu Dubai eleyii ti won ko ti kapa ina naa. Bi a se n ko iroyin yii lowolowo, aja bi ogun ti jo kanle. Bakan naa ni ina naa n tesiwaju si i.About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*