Home / Àṣà Oòduà / INEC ti kede Yahaya Bello gege bi gomina tilu dibo yan nipinle Kogi

INEC ti kede Yahaya Bello gege bi gomina tilu dibo yan nipinle Kogi

Ajo INEC ti kede Alh. Yahaya Bello gege bi gomina tuntun tilu sese dibo yan. Ninu eto idibo eleyii ti asekagba re waye lana ni Bello lati inu egbe onigbale, APC, ti ni apapo ibo 247,752. Nigba ti PDP ni apapo iye ibo 204,877.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo