Home / Àṣà Oòduà / Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi

Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi

Olotu: ekasan ooo eyin ara ile,asiku asiko yin, eledua yowa pelu gbogbo wa o,ase. Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro egbo bose wic….Gbogbo eyin ebi mofe ki e fi ise yin bura fun mi pe ti moba so e ni lemi jade ni ile oko mi,e sini jeki iya oko mi wa gbe ile wa.

 
Olotu:arabinrin yin wipe awon ebi mase,leyin re lotun tesiwaju pe….Se eri emi te woyi mi o ki se eyan lasan,eranko igbo ni mi,se e wari iya ti e woyi babalawo kan ti sofun iya yi wipe oko mi loma seku pa,inu iya nan baje tori ninu gbogbo omo tobi oko mi lo feran ju,iya yi bere pe kini oun lese si,baba nan wipe kosi ikan tole sesi afi toba le koko pa omo nan,tori iya yi nan lopa iya re.Asiko esan si tide,leyin opolopo ironu ni iya yi gba lati se,idi niyi ti o fi fe magbe lodo wa.
Olotu;too,eyin ara ile oro leti gbo lenu iyawo yi,kini ki awon ebi se ?,iwo ti o baje abiyamon gidi fi owo di ori remu,koni oloun mafun mini omo ti yo pami,masi fun mi ni iya ti yo pami.Iwo odo wipe eledua maje siyan.Ire ooooooo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Arápájà

Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí

Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí Ọrẹ Akínṣọlá Ṣé bóṣe wu Ọlọ́run Ọba ní-ín sọlá, èèyàn tó bá wù Ú ní-Ìn ṣe lógo.Igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nígbààa kan, Ọ̀gbẹ́ni Taofeek Arapaja, ti jáwé olúbori sípò Ìgbákejì Alága ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní Gúúsù ilẹ́ wa, ó sì fẹ̀yìn alátakò rẹ̀ tóun náà jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀sun tẹ́lẹ̀rí, Ọmọọba Ọlágúnsóyè Oyinlọlá, janlẹ̀. Iṣẹlẹ yii waye lowurọ ọjọ Aiku, ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu kẹwaa yii, lasiko ti wọn n ka ...