Home / Àṣà Oòduà / Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ìgbáradì ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo àti Òǹdó lọ́wọ́–INEC

Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ìgbáradì ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo àti Òǹdó lọ́wọ́–INEC

Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s’ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò dí àwọn lọ́wọ́ rárá láti múra sílẹ̀ de àṣeyọrí ètò ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àti Ẹdó.

Wọ́n ní kò sí ayípadà kankan lórí àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ ní gbígbé láti ṣètò ìdìbò gómìnà àti àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn ìpínlẹ̀ méjéèjì náà..

Ìpínlẹ̀ Edó wà ní Gúúsù Gúúsù Nàìjíríà nígbà tí ìpínlẹ̀ Òǹdó wà ní ìwọ̀ oòrùn Gúúsù Orílẹ̀ yìí.

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.