Home / Àṣà Oòduà / Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.

Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.

    Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni won ti gbé lo sí ilé ejó .

Won fi èsùn kàn wípé ó pa oko rè. Maryam kò le mú òrò náà móra ni ó bá bú sígbe gbàmù nígbà tí ó dì mó omo rè osù méfà móra.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.