Home / Àṣà Oòduà / Mike Ozekhome se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún(60).

Mike Ozekhome se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún(60).

Gbajúgbajà amòfin oloyè Mike Ozekhome, SAN se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún ni ilé-ìtura Sharaton tí ó wà ní ìlú Abuja nínú àwon tó lo ni Ààre télè Goodluck Jonathan, ìyàwó rè Patience, igbákejì Ààre ilé ìgbìmò asòfin Ike Ekweremadu àti àwon èèyàn míràn…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.