Home / Àṣà Oòduà / “Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .

“Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .

     Òkan lára àwon Olólùfé obìnrin tí ó ti nífèé Wizkid ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi èhónu rè hàn wípé òun nífèé Wizkid sùgbón ó so wípé ànfààní nlá ni kí Wizkid fé òun kí ó sì já òun kulè. Nígbà tí Wizkid yóò fèsì lórí èro ayárabíàsá tí ó ro arábìnrin yí kí ó má se nífèé òun rárá nítorí òun ma ja kulè.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.