Home / Àṣà Oòduà / Moki gbogbo eyin Omo oodua pe asiku imura idibo tinbo yi

Moki gbogbo eyin Omo oodua pe asiku imura idibo tinbo yi

Eje kasora dada oledumare  koni fi aburu kan wa .ki okunrin merin 4 ki oso eni ti afe ki owa lori aga agba loke loun .ki obirin merin 4 na funwa ni ti won .awon agba ni oun eyan loun oun olorun.eje kadibo larin arawa naa kamo eni ti yio wole .ki eniyan merin lokunrin .ati lobirin .kiwon so ero inuwon tagan na ni efe .ninu won. BUARI .JONATAR…
Ki ato wa dibo  gomino .OYA KADIBO..TANI TIRE

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo