Home / Àṣà Oòduà / Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Ìyáwó Oritsefemi, Nabila, wà ní orí ìkúnlè níwájú oko rè nígbà tí ó bá Dólà fun níbi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó.
Èyí mà wuni o, e wo oko tí orí rè wú tí ó sì ná ìyàwó rè lówó.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo