Home / Àṣà Oòduà / “Ó ye kí obìnrin náà ní ànfààní àti fé okùnrin Mérin” òdóbìnrin mùsùlùmí yí ló so béè.

“Ó ye kí obìnrin náà ní ànfààní àti fé okùnrin Mérin” òdóbìnrin mùsùlùmí yí ló so béè.

    9Ò n lò èro ayárabíàsà (Twitter) tí a mò sí Halima ni òpò ti takò látàrí wípé ó so wípé ó ye kí won gba obìnrin náà láyè kí won fé ju okùnrin kan lo.

Ní òtító olórun kò fi àyè gbà kí obìnrin fé ju okùnrin kan lò, ó sì wí “mé” fún okùnrin sùgbón ó fi “sùgbón” si tí òpò okùnrin kò sì mo nkan tí “sùgbón” náà túmò sí.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.