Home / Àṣà Oòduà / Òdómobìnrin odún mókàndínlógún pín àwòràn ilé tí ó rewà tí sugar daddy rè rà fun .

Òdómobìnrin odún mókàndínlógún pín àwòràn ilé tí ó rewà tí sugar daddy rè rà fun .

      Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n fi ilé bògìnì tí sugar daddy rè gbà fun hàn .

Nígbà tí enìkan bi lérè wípé sé ó ti fi sugar daddy rè sílè, rí ó sì dáhùn wípé rárá …

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.