Home / Àṣà Oòduà / Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun

Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun

E ku odun tuntun. Odun ayo ati igbega ni yoo je fun gbogbo wa.  Ase.
Odun 2016 yoo dun bi oyin. Bee ni. E je ki eleyii je ero yin. Kosi tun maa jeyo ninu awon oro enu yin nigba gbogbo. E ma je ki iriri ijakule ateyinwa je oun ti yoo maa wa lenu yin nigbogbo igba ti e ba n ro nipa ojo ola. Ohun to ti sele si yin tele tabi ohun ti n sele lowolowo ko ni ohunkohun se pelu ohun ti yoo pada sele. Sugbon ewu to wa nibe ni wi pe, e le se akoba fun igbe aye yin, nigba ti awon oro to n jade lenu yin ba lodi si aye yin.

Oro enu lagbara, e je ka sora nipa bi a se n lo. Ki a ma ba lo oro enu lodi si igbe aye wa . Emi nigbagbo wi pe odun 2016 yoo dun fun mi ju 2015 lo. Ire ayo mi yoo de, awon eniyan yoo si ba mi yo.
Ise mi ati okoowo mi yoo tun goke agba lodun 2016. Ati emi ati awon ololufe mi kari aye, iwaju la a ma lo. Oke oke si ni owo wa yoo maa wa nigba gbogbo. Ami

E ku odun tuntun.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo