Home / Àṣà Oòduà / Olojo Ibi Toni -04.09.2016

Olojo Ibi Toni -04.09.2016

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Daud Adewuyi ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata.

Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan.  e o ni ba won na oja warawara nile aye beeni e o si ni dagba yeye, gbogbo ohun rere ti n mu’le aye rorun fun eda ni Olodumare  yoo fi jinki yin. E o gbo, e o to, e o fewu pari, e o ferigi jobi, e o gbele aye sohun rere bi o ti wa wu ki e pe to laye e o ni f’oju mo saare omo lase Edumare.

Kabiyesi ati awon Oloye ati gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata nileloko nki yin wipe IGBA ODUN, ODUN KAN NI O….

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.