Home / Àṣà Oòduà / Orunmila O jiire l’oni o! Bi Àlà tii ji l’Ode Akure!

Orunmila O jiire l’oni o! Bi Àlà tii ji l’Ode Akure!

Okanran Meji
II II
II II
II II
I   I
Ifa ni:
Bi a ba ti ko ni bee ni a n ki ni
Bi a ba ti ki ni bee ni a n je ni
Orunmila pele o
Omo elepo lopo ti o j’adi
Orunmila pele o
Ekun j’eran sun!
Ifa says:
One’s appearance determines the way he/she is greeted
One’s style of greeting determines
The style of response
Honour to Orunmila
The sole palm oil magnate
Who never eats palm kernel oil (adi)
Honour to Orunmila
The Tiger who forever feeds on dinners of meat!
Orunmila has this oriki because
there’s never a day that animals are
not sacrificed to Him; eku, eja,
eye, snails, goats, pigs etc
#Ifangelism.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá

Looking at the Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá, it could be said that sometimes our detractors feel they are hurting us but they don’t know they are pushing us to wealth. Just listen to this stanza from the Odù. Òtééré ilè ńyóÒtèèrè ilè ńyòIlè ńyó ará iwájúÈrò èyìn e kíyèsí ílèAdífá fún Ìwòrì tí yóó tarí Ogbè sínù àbàtàbútú ajéKòìpé kòìjìnà, Ogbè ló wá jìn sínú ajé gbugburu Òtééré, the ground is slipperyÒtèèrè, the ground is difficult ...