Home / Àṣà Oòduà / Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntun

Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntun

Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntum.
Olórin, peter Okoye tí a mò sí Mr.P tí ó ti fi èkejì rè sílè, Paul Okoye àti alákoso won, Jude Okoye ti gba alákoso tuntun.
Ó sì ti pín àwòrán náà sí orí èro ayélujára (Instagram). Kí èsù má da àrin won rú.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.