Home / Àṣà Oòduà / Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19

Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19

Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i

Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.
Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to koja lo.
Arun yii ko mu oun nikan, o tun mu mefa miiran ninu ebi re. Oni yii ni ori ko alagba naa yo pelu awon ebi re mefeefa.
Oluulu Naijiria, Abuja ni won ti ģba iwosan tiwon, ni ibi ti won ti n se itoju awon ti ajakale naa ba ko lu.


Gbogbo awon ebi, ore ati ojulumo lo ti bere si ni ki alagba naa ku oriire. Nitori pe aisan naa buru de bii wo pe ko mo olowo bee ni ko mo talaka sugbon Eledua ko won yo.

Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.