A gbó láìpé la gbó wípé Wizkid ti kí omo tuntun káàbò tí alákoso rè, Jada Pollock bí fun. Òótó ni èyí, Wizkid ti ri dájú wípé omo òun ni , ó sì ti so omo náà l’órúko “Zion Ayo Balogun”.
A kí o kú oríre starboy, kí ire náà kárí.

Tagged with: Àṣà Yorùbá