Home / Idile Gisiti

Idile Gisiti

Arápájà

Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí

Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí Ọrẹ Akínṣọlá Ṣé bóṣe wu Ọlọ́run Ọba ní-ín sọlá, èèyàn tó bá wù Ú ní-Ìn ṣe lógo.Igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nígbààa kan, Ọ̀gbẹ́ni Taofeek Arapaja, ti jáwé olúbori sípò Ìgbákejì ...

Read More »
sanwoolu

Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi

Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé wọ́n ní ìgbẹ̀yìn làásìgbò kan kìí bímọ tó rọ̀. Làásìgbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó láìpẹ́ yìí ti mú kí Gómìnà ìpińlẹ̀ náà, Babájídé Sanwó-Olú ó pàsẹ ...

Read More »

Eyin eniyan e wo E-moni(E-money) ninu photo titun re.

Alaga ti Ẹgbẹ eka marun apapo , wuni ninu poto re titun ti o sese ya.

Read More »

E fun irun yi loruko ?

Read More »

Araga ni foto Yemi Alade yii

#Orisanla omoge onidodo

Read More »

Foto Mercy Aigbe meje (7) to ta lenu bi ataare

Ti ija ba wa ni be, e je a pari kia. Awon Yoruba si bo won ni tomo eni ba daa kawi, kii se ka fi saya. Egan ni he, Mercy Aigbe ta lenu bee lodun yungbayungba.  Olayemi ti mo ...

Read More »

[Foto] Aso oge Toyin Aimakhu le ku! #Igo loju omo odaran

#ToyinAimakhu Se igo yii o wa poju?

Read More »