Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 2)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn

Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùnAruku madẹgbẹ Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo

Read More »

Ìwúre Toni

Ikú tó yọ lóòré ńkọ́ Àrùn tó yọ lóòré ńkọ́ Ẹjọ́ tó yọ lóòré ńkọ́ Òfò tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí kọ̀wun, àyà mí kọ̀wunMoti jẹ kọ̀ǹkọ̀ mo ti kọ̀ Owó,aya, ọmọ,gbogbo ire tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí gbàwun, àyà mí gbàwunMoti jẹ ...

Read More »

O lápátí

Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ ...

Read More »

Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún ...

Read More »

Iba Eleiye

Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...

Read More »

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. ...

Read More »

Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa

Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní ...

Read More »

Tàgiiri

Tàgiiri ma yí nìsó Ara rẹ lokùn Ara rẹ ní ajé gbe ńso

Read More »

Ẹ̀yẹ̀lé

Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, Rirọ lonrọ àdábà lọrún, Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀,

Read More »

Ifá naa ki bayi wipe: Osa Alawure (Osa Otura) – Otua Meji

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, adura wa yio gba, ori buruku koni je tiwa loni o Àse. Mo nfi akoko yi nki gbogbo onisese patapata kaakiri agbaye wipe aku aseyori odun ifá agbaye o , a ku odun a sin ku iyedun o, emin wa yio se pupo re ninu ola ati idera lase Eledumare.

Read More »