Home / Tag Archives: Ooduarere (page 3)

Tag Archives: Ooduarere

Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan

Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan Ààrẹ Buhari ti pe Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀,láti báa kẹ́dùn lórí ìkọlù àwọn agbébọn tó wáyé ní Òtuòkè tíí ṣe ìlú abínibí rẹ̀ nípìńlẹ̀ Bayelsa. Nínú ...

Read More »

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki

Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti DasukiLati owoYinka AlabiIjoba apapo orileede Naijiria ni o ti ni ki Ogbeni Omoyele Sowore ti o je oludari “iroyin ayelujara Sahara” ati Sambo Dasuki ti o je oluba-Aare damoran pataki (NSA) nigba isejoba Goodluck ...

Read More »

Mo ti pàṣẹ fún àjọ DSS láti tẹ̀lé àṣẹ ilé ẹjọ́….Abubakar Malami

Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.

Read More »

Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú

Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...

Read More »

llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́

llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní ilé tí a fi itọ́ mọ, ìrì ni yóò wo. Ọbẹ̀ tí a fi èké pilẹ̀ ẹ rẹ̀, í í ru ...

Read More »

Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́

Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ìgbésẹ̀ òhun ìhùwàsí oníkálùkù láàyè, ìtàn ló ń kọ lóké eèpẹ̀.Tẹbi tara tọ̀rẹ̀ àti àwọn èèkan nísẹ́ Ìjọba ló péjú láti ṣé ajọyọ̀ ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bí ọdún karundinlọgọrin ...

Read More »

E̩ tu èékánná lára S̩owore – Ilé-e̩jó̩

Ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja lo pase fun ijoba apapo pe ki won yokun lorun Ogbeni Omoyele Sowore.Sowore ni o n gbimo lati se iwode Kan to maa mi ilu titi. Lati igba naa ni ijoba apapo ...

Read More »

Awa Omo Oudua Rere: E Da Epa Owe Kan To Ba Oro Aja Lo

Owe Yoruba

Read More »