Home / Àṣà Oòduà / Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs

Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs

Awon ajo asobode ile Nigeria ti gbogbo eniyan mo si Customs ni won n ba awon oniroyin soro ni ipinle Adamawa pe, ko si ile tabi soobu ti awon ko le ja tabi fo ti o ba ye.
Won ni gbogbo eda tabi onisowo fayawo ti awon ba kefin pe o keru wole lona aito ni awon le fagidi ja ile tabi soobu re ki awon si lo awon ero ofin naa lo.


Gege bi iko ti Ogbeni Kamarudeen Olumon dari ni ipinle Adamawa se salaye. O ni bi awon se n ge awon onifayawo lowo ni won n bo oruko.
O ni gbogbo ogbon alumokoroyi ni won mo ti won si fi n koja wole. O ni ofin abala 147 ajo Customs gba awon laaye lai gbase lati ibikankan lati lo ko iru oja bee.

Awon ara oja Mubi ni ipinle naa rawo ebe si ijoba apapo ki o jowo si oju aanu wo awon nitori pe opo onisowo lo dawojo lati lo ra oja ti awon ajo naa gbese le. Won ni awon ko tun je fi iru aso bee seegun mo.
Awon ajo yii ko gbo ebe rara, gbogbo iresi, ororo ati awon nnkan ile okeere miran ti won ba ninu oja Mubi naa ni won ko.

Yinka Alabi

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo