Home / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti bobo yii se fun afesona re nita gbangba

E wo ohun ti bobo yii se fun afesona re nita gbangba


Laaarin ile itaja nla kan niluu Warri, bobo yii kunle fun ololufe re. O mu oruka ife jade lapo, o si wi bayii wi pe: “Joo ololufe mi, nje o gba lati je iyawo mi?”

Opolopo awon eniyan ti won raja lowo ni won dawo duro, ti gbogbo eniyan si teju mo won.

Ori omobirin ti bobo naa kunle fun loju gbogbo aye wu bi gaari Ifo, terin-toyaya lo fi na ika re siwaju fun bobo naa. Nigba ti afesona re si fi oruka ife, ti won fi goolu se, sibi to ye.

Ibere ife a maa dun bi oyin, adura mi ni wi pe ki ife naa o ba won kale.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

tems

Mo setán láti kú’ – Tems

Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo kaakiri orile ede sile fun R&B. Tems wi pe oun ni igbagbo pupo ninu ara oun to bee ti oun ko bikita bi oun o ba “je nnkankan tabi da enikeni” pelu R&B. Olorin ‘Essence’ naa so pe oun kan ...