Don't Miss
Home / Àṣà Oòduà / Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?

Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?

Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije gege bi omo ile igbimo asofin ipinle Ogun boya leyin Gbenga Adeboye Abefe lo ti kose sorosoro. Ibeere yii lo jeyo nipa akiyesi wi pe ohun Wale Dada jo ti iru ohun ti Gbenga Adeboye n lo nigba aye re.

Olootu fiimu Felefele Laye salaye wi pe bi o tile je wi pe oun ti ni ajosepo pelu Gbenga Adegboye ni awon akoko kan ri nigba aye re, sugbon kii se Alhaji-Pastor-Oluwa lo ko ohun nise sorosoro.

Taa wa lo ko Wale Dada nise sorosoro? Inu fidio yii lekunrere alaye wa.

Bakan naa, ninu iroyin tuntun mi-in, Adewale Dada parapo mo awon omo Naijiria rere lati seye ikeyin fun Mama HID aya Awolowo to rebi agba n re.

 

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Agun Baniro So wipe, Ilu Eko ni Olulu Ipinle Abuja Wa

Aara meriri, egbani eleja, arabirin kan ti o un se agun ba ni ro so wipe olulu ipinle Enugu Ni Anambra, ati pe o tun so wipe, olulu ipinle Eko ni ilu Abuja.  Eyin je oun ti o bani ninu je wipe akeko gboye ni ile eko giga, kuna lati so idaun si awon ibere won yin. English Version Continue after the page break