Home / Àṣà Oòduà / Àwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.

Àwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.

Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni tí kò ní opolo.
Kò kúkú sí ohun tí a kò ní rí tán, kárí kâ fojú fò lópò, àfi kí olórun gbà wá.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo