Home / Àṣà Oòduà / Ambode naa ti pada si ni se bi Fayose: Gomina Eko ti pada sigboro aye

Ambode naa ti pada si ni se bi Fayose: Gomina Eko ti pada sigboro aye

Gomina Akinwumi Ambode lo da awako akero kan ti n wa moto lona aito duro lonii nigboro Eko.  Se kii se wi pe gomina naa fe ma se bi Ogbeni Ayodele Fayose?

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo

Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo oniyawo? Eniwee, mo laiki tattoo to wa lapa ati owo madamu o. Tattoo naa fine gan-an. Eni to ba si ri Ogbeni Habib, e wi fun wi pe Olayemi Oniroyin n bo l’Alausa lola fun awon oro to se pataki.