Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.

Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.

Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní òtá tí ó pò jaburata, òun sì ní láti ba ségun won.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo