Home / Aarin Buzi / Tonto Dikeh ki Mercy Johnson pe ‘oku orire fun ipo titun ti Gomina Kogi sese yan si’.

Tonto Dikeh ki Mercy Johnson pe ‘oku orire fun ipo titun ti Gomina Kogi sese yan si’.

Awuyewuye ija ti oun lo laarin awọn oṣere Tonto Dikeh ati Mercy Johnson, Tonto Dikeh ti toro aforiji lori awọn gbólóhùn o ṣe nipa ọmọ rẹ ati awon oro miran to ti so ni odun die seyin. Mercy Johnson gba ebe e, awon mejeji si tọ akọroyin lo, lati fi ha wipe ni otito ni won ti pari ija won. Tonto Dikeh , si ki Mercy Johnson noni lori ipo titun eyi ti unse biba gomina jiroro lori Asa ati ise, ti gomina ipinle Kogi sese fi je.

 

English Version–>

Continue after the Page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*