Two Ikò Boko Haram ti fi ojú winá ogun won sì ti bá ogún lo, tí ojú won sì rí méwàá ni ojó kejìlélógbòn osù kokànlá odún 2018 nígbà tí won tún fé se bí ìse won ní Arege ní ìjoba ìbílè Mobbar ní ìpínlè Borno.
Àwon akoni wa ti kojú ogún dàwón won sì ti jéyán won nísu.
Home / Àṣà Oòduà / Àwon Jagunjagun tí a mò sí Soldier ti pa ìko àwon Boko Haram ní Arege, Borno, tí won sì gbà àwon ohun ìja olóró ní owó won.
Tagged with: Àṣà Yorùbá