Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó.
Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó òun ati oko àfésónà rè, eléyìí tú yani lénu oo.
![](http://ooduarere.com/wp-content/uploads/2019/07/IMG_20190706_203737-1-311x330.jpg)