Home / Àṣà Oòduà / Awon Foto Lati Ibi Ijamba Oko Ofurufu Awon Omo Ologun Niluu Kaduna

Awon Foto Lati Ibi Ijamba Oko Ofurufu Awon Omo Ologun Niluu Kaduna

Awon aworan Oko ofurufu Dornier 228 ti awon omo ologun ile Nigeria ti a kede wi pe o jabo loju orun laaro oni ni yii. Awon eniyan meje ti won wa ninu oko ofurufu naa lo parun patapata.About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

tems

Mo setán láti kú’ – Tems

Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo kaakiri orile ede sile fun R&B. Tems wi pe oun ni igbagbo pupo ninu ara oun to bee ti oun ko bikita bi oun o ba “je nnkankan tabi da enikeni” pelu R&B. Olorin ‘Essence’ naa so pe oun kan ...