Home / Àṣà Oòduà / “B’éni l’ówó bí ò n’íwà, owó olówó ni

“B’éni l’ówó bí ò n’íwà, owó olówó ni

B’éni l’áya bí ò n’íwà, aya aláya ni
B’éni bí’mo bí ò n’íwà, omo olómo ni
If one has money but lack character, it’s someone else money
If one has wife but lack character, it’s someone else wife
If one has children but lack character, they belong to someone else.”
Iwa is the ultimate weapon we use to acquire all good things of life.
I pray our character won’t destroy our destiny.”
~Okanran Odi.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo