Home / Àṣà Oòduà / Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩

Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩

Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩

Yorùbá bò̩, wó̩n ní ‘àrà ò kì ń tán nínú alárà nígbà kankan’. Gbajugbaja Semeyo Dino Melaye tí gbogbo ènìyàn mò̩ bí e̩ní mo̩ owó tún gbé àwo orin jáde nípa olórí àjo̩ EFCC, alàgbà Ibrahim Magu.

Ò̩gbé̩ni yìí ni o ǹ jé̩jó̩ orísìírísìí ló̩wó̩ ìjo̩ba báyìí.
Àyàfi kí e̩ gbó̩ àwo orin náà fúnra yín ….

Yínká Àlàbí

About ayangalu