Home / Àṣà Oòduà / Eku Dede Asiko  Yi Ni Gbogbo Ibi Ta A’Ba Wa o

Eku Dede Asiko  Yi Ni Gbogbo Ibi Ta A’Ba Wa o

Oruko mi ni TINUKE mofe ki eyin omo ilu yi gbami ni yanju lori oro yi ni ooooo

Lati bi osu marun se yin ni ago ibani soro kan man pe mi Ti eni yen ba pe mi EPE nla Loman se funmi. Ti moba pe pada EPE na tun ni in. Ana ojo isinmi yi ni antimi wa si odo mi. Won ni kin mu awon de ibi ti mo tin se irun mi. Mo mu won dede mi o ba oni bara mi nile. Eyin omo se e funmi ni ago OGA yin kin pe. Ni Igba ti ma gba ago ti won funmi ago ti o man pe ni ooo. Mo bere lowo awon omo se yi dada won ni oga awon loni o. Ago ebi re ni yen. Mowa lo ogbon fun awon omo yi. Won wa tu asiri OKO mi ati OGA won funmi.
Bi mose dele mo bere lowo OKO looto ni won fe ara won o. Mo pariwo haaaaaa okunrin apayan mani yin oooo. Eni ti o bami se irun ori mi.
Akobi omo binrin yi odo OKO mi lo tin kose ti omo na si n wole mi dada. Gbogbo Ile se mi o ti tenin ti IKU bai eyin temi. E sanumi ooo. Kini kin se bai ooo. Oro yi si n gbona lowo bai-bai ooooooo

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo