Home / Àṣà Oòduà / Ènìyàn O̩gbò̩n Ti Lùgbàdì Coronavirus Ni Naijiria

Ènìyàn O̩gbò̩n Ti Lùgbàdì Coronavirus Ni Naijiria

Ènìyàn o̩gbò̩n ti lùgbàdì coronavirus ni Naijiria
Ìròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí

Afi ki Eledua maa ko wa yo ni orileede yii. Bi ere bi awada, ajakale arun kogboogun (covid-19) ti mu eniyan ogbon di asiko ti a n ko iroyin yii jo ni ojo aiku, ojo kejilelogun, osu keta odun 2020.

Gege bi ajo to n mojuto eto ilera naa, N C D C, (Nigeria centre for disease control) se gbee sita.
Won ni mejilelogun lo yoju ni ipinle Eko, merin ni Abuja, meji ni Ogun, okan ni Oyo nigba ti okan to ku naa wa lati Ipinle Ekiti.

Gbogbo ileewe lo ti fere wa ni titi pa, opo osise lo ti wa nile sibe won ni ki a je ki imototo wa po sii lasiko yii.

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.