O ṣọ #50 nu, ẹni to ri owo na wa ra nkan #10 ni ilé itaja rẹ o si fun ni #40.
#Ibeere: elo ni iye ti o padanu lapapọ?
O ṣọ #50 nu, ẹni to ri owo na wa ra nkan #10 ni ilé itaja rẹ o si fun ni #40.
#Ibeere: elo ni iye ti o padanu lapapọ?
Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...