Home / Àṣà Oòduà / Iwure Ojo Aje 3/10/2016

Iwure Ojo Aje 3/10/2016

Ekaro oo
se dara dara laji lowuro eni o
gege bi emi na se ji oo
toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi tinje orogbo kiadupe ore igba gbogbo kiawa bere fun alekun ore :- Oro yi se pataki tiabale se akiyesi ee . Adura wa a gba o
Moki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye oo ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo

Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA O.)
(.OPE LANDU LOWO ENI TOSE NI LORE.)
olodumare adupe o
irunmole igbamole amo lore o
iyin ati aponle fun ojishe nla julo orunmila(a.t.s.)
adupe pe asun lati asale ana
awaji si imole alaye olodumare adupe o
ape apawa osegbe
ape ese wa osegbe
ala oju wa ariran
ala enu wa afi soro
eti wa gbo oro omonikeji wa
olodumare je kiale dupe ore miran lowo ee nipa iyonda ojishe nla julo orunmila(a.t.s.)

(IWURE OWURO OJO AJE.)
Awa mari ti aje se o
Awa afi ile wa se ibugbe o
Akoni wa owo ti o
Olodumare alana ririse kan wa o
Aje awa wa ri o
Amari omo olokun te nifa o
Pasan aje koni na wa o
Ama ni owo lowo akoni ni lorun o
Amari anu olodumare gba o
Ibikibi ti egbe wa tin na wo akoni na agidi ni bee o
Owo lan fin logba amari owo saiye o
Eni iwaju eni kokan wa koni di ero eyin o
Aje oguguluso oniso iboji yiofi iso sile ati ona wa oo
BENI YIORI O
LAGBARA LOWO OLODUMARE
NIPA ASHEE ENU IRUNMOLE IGBAMOLE
LOLA TITOBI ORUKO OJISHE NLA JULO ORUNMILA(A.T.S.)
(…Emi Ni Ti Yin Toto…)
Ojogbon Awo Mimo
Afifadara Kinnihun Orunmila

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo