Home / Àṣà Oòduà / Jonathan sàbẹ̀wò sí Buhari

Jonathan sàbẹ̀wò sí Buhari


Ara iroyin yajoyajo to wole ni abewo ti Aare ana, Omowe Goodluck Jonathan se si Aare Mohammadu Buhari ni Aso Villa to wa ni oluulu Naijiria ni Abuja.


Ipade bonkele ni ipade yii nitori pe awon mejeeji tilekun mori ni, won ko si ti so nnkankan fun awon oniroyin nipa ipade pajawiri naa.

Láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

About ayangalu

x

Check Also

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn

Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá